Àwọn ìbéèrè ti a man n bere lore lore


Ti iwo ba ti ni igbala, nje igbala ayeraye ni?

Kini yio sele lehin iku?

Nje igbala ayeraye wa ninu Bibeli?

Kini Kristiani mo nipa ipara eni? Kini Bibeli so nipa pipa ara eni?

Nje o ye ki ababirin je alufa / oluso-aguntan? Kini Bibeli so nipa obinrin gege bi iranse?

Kini Bibeli so nipa eya igbeyawo?

Kini pataki irubomi Kristiani?

Kini Bibeli so nipa Metalokan?

Kini Bibeli so nipa eyi? Iru ipo wo ni enia le wa lati fe elomiran leyin igba ti o ko ekeji re sile?

Kini Bibeli so nipa idamewa Kristiani?

Kini Bibeli so nipa ibaraasun siwaju igbeyawo?

Kini Bibeli so nipa oti mimu/ waini? Nje ese ni fun kristiani lati mu oti/tabi waini?

Ibo ni Jesu wa ni ojo meta larin iku ati ajinde?

Kini Bibeli so nipa tete-tita? Nje tete-tita je ese?

Kini ebun ede miran soro? Nje ebun ede yi wa fun wa lode oni? Kini adura ede miran soro?

Kini Bibeli so nipa eranko bi alangba yi? Nje eranko nla atijo yi wa ninu Bibeli?

Kini Bibeli so nipa Isami ara / ebu?

Nje eranko / ma n lo si orun? Nje eranko / ni emi?

Tani iyawo Kaini? Nje iyawo Kaini je gege bi aburo re?

Kini Bibeli so nipa eyi? Nje eyi je ese?

Ibalopo- Nje o je ese gege bi Bibeli?


Àwọn ìbéèrè ti a man n bere lore lore