settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa Isami ara / ebu?

Idahun


Iwe Majemu lailai pase wipe awon omo Isreali, “ Eyin ko gbodo sin gbere kan si ara nyin nitori oku, beli enyin ko gbodo ko ami kan si ara nyin: Emi li OLUWA’( Lefitiku 19:28). Nitori naa, gege bi pe awon onigbagbo o se wa labe ofin Majemu (Romu 10:4; Galatia 3: 23-25; Efesu 2:15), nipa pe ofin kan wa nipa eyi o ye ki a bere ohun kan. Iwe Majemu titun o so ohun kan nipa wipe boya onigbagbo le lami tabi ni ebu.

Gege bi ila ati ebu ara, eyi je ona ti a le fi so fun Oluwa ki o lo eyi lati se ohun rere re. “Nitorina bi enyin ba nje, tabi bi enyin ba nmu, tabi ohunkoun enyin ba nse, e ma se gbogbo won fun ogo Olorun” (1 Korinti 10:31). Bibeli o pase wipe a ko le se eyi, ko si so naa wipe Olorun fe ki a se.

Ohun miran ti a ni latir o naa ni niwontunwosin. Bibeli ni wipe ki amura daradara ( 1 Timoteu 2;9). Iwontunwosin imura wa ti Oluwa fe niwipe ki a bo ara pelu aso ni ibi ti o ye ki a bo. Sugbon, eyi ki se wipe ki o mura lati je ki awon enia ma wo o. Awon ti o ba mura o ni lati je ki awon enia ma wo won nitori nkan ti won wo. Ami ati ebu ara si je ohun ti an soro nipa. Nitori naa, ami ara ati ebu k oto si omo Olorun.

Eyi ti a fi ni oye naa ni wipe, igbati Bibeli ko so ohun kohun nipa re, o ye ko ye wa wipe eyi si je ohun ti Oluwa ko feran rara. “Ohun ti ko je nipa igbagbo ese ni” (Romu 14:23). A ni lati ranti wipe ara wa, emi wa, ti di irapada, o si ti di ti Olorun. Bi o ti leje wipe 1 Korinti 6:19-20 ko so ni pato nipa re, ko si fun wa ni ipilese re, “Tabi, eyin ko mo pe ara nyin ni tempili Emi Mimo, ti mbe ninu nyin, ti enyin ti gba lowo Olorun? Enyin ki si ise ti ara nyin, Nitori a ti ra nyin ni iye kan: nitorina e yin Olorun logo ninu ara nyin, ati ninu emi nyin, ti ise ti Olorun.” Eyi je otito lati mo ohun ti a n se, ibi ti asi n lo pelu ara wa. Ti ara wa b aje ti Olorun, a ni lati bere fun aye ki a to fi “ami” tabi ebu si.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa Isami ara / ebu?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries