settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa tete-tita? Nje tete-tita je ese?

Idahun


A ko le so wipe tete-tita je “owo ewu lati le je ki o po nigbati o ba fi die sile. Bibeli ko so ni pato wipe tete-tita tabi loteri. Sugbon Bibeli fi ikilo fun wa wipe ki a sa fun ife owo ( 1 Timoteu 6:10; Heberu 13:5). Bibeli si so fun wa wipe ki a sa fun ona ti a fe gba lati “ni owo kiakia” (Owe 13:11, 23:5; Iwasu 5-10). Tete-tita je nipa ife owo o si ma n wo awon enia loju lati tete ni owo kiakia.

Ki lo de ti tete-tita o fi dara? Tete- tita je ohun ti o le nitori pe e kon kon ni a n se, a n so owo nu, sugbon ki se ohun “buburu.” Awon enia ma na owo ni ina kuna. Tete-tita o da inakuna bi wipe ki a lo wo aworan, ki a je onje ti o won, tabi ka ra ohun aiwulo. Sugbon naa, nitoripe a naa owo ni inakuna ko so wipe tete-tita dara. A ko gbo se idahoro owo. Owo pupo ti a ba ni, a ni lati fi pamo fun ojo iwaju tabi ki a fi se ise Olorun- ki se fun tete.

Tete-tita ninu Bibeli: Bibeli ko so nipa tete-tita, sugbon o soro nipa ere “alaibapade.” Fun apere, wo se ibo ni Lefitiku lati mu larin eranko ti wo n fi se etutu, Josua se ibo lati pin ile fun awon omo Ireali. Nehemiah se ibo lati mu eniti yio gbe ni inu Jerusalemu tabi eni ti yio gbe ni ita. Awon Aposteli se ibo lati le fi elomiran ranpo Judasi. Owe 16;33 wipe, “A se keke da si isepo aaso; sugbon gbogbo idajo re lowo Oluwa ni.” Ko si ibi kan ninu Bibeli ti o so fun wa wipe tete-tita je ohun ti o dara tabi ohun ti luwa fe.

Ile tete ati tete-tita: Ile tete ma n lo orisirisi ona lati je ki awon enia na owo won. Won ma n fun awon enia ni ohun ti ko won tabi oti ofe ti o n fa imuki mulati le naa owo re. gbogbo ohun ti o wa ni ile tete ni ko dara afi ti o ba ko fe lo woran nikan. Won tun fe se ni daradara lati ma ran awon enia lowo ninu eko. Sugbon bi a ti mo awon ti on tele ni owo naa lati naa. Iwa nipa wipe a fe di olowo ti o wowon loju lati ni owo. Eyi si ti so awon elomiran di ohun ibanuje nitoripe a tile se aseyori ninu re kere gan.

Ki lo de wipe owo ti a ba ni lori re ko je ohun ti Olorun fe: Orisirisi awon enia ni o n ta wipe ki won le fun ile ijo tabi ki won se ohun dardara. Ti eyi ba si je ohun didara, awon die lo le se aseyori ninu re fun Oluwa. A si mo wipe awon ti o je tete yi pelu owo nla , wa ninu irora nisin yi ju igba ti won ti won ni lo. Awon die ni o fe owo naa se ohun rere. Oluwa ko fe owo wa lati se ise ijo re. Owe 13:11 wipe, “oro ti a fi iwa asan ni yio fasehin; sugbon eniti o fi ise-owo kojo ni yio ma po si i.” Oluwa ni agbara yi o si pese fun ijo re ni ona otito. Nje a o so Oluwa di olododo ti a ba fun ni owo ogun oloro, tabi owo ti a ji ni ile owo? Be naa ni Olorun ko fe owo ti a ji lati owo awon alaini nitori oju kokoro.

1 Timoteu 6:10 so fun wa wipe, “ife owo ni ipinlese ero buburu; eyiti awon miran nlepa ti a si mu won sako kuro ninu igbagbo, nwon si fi ibinuje pupo gun ara won li oko.” Heberu 13;5 wipe, “ki okan nyin ki o mase fa si ife owo, ki ohun ti e ni ki o to n yin; nitoripe on tikarare ti wipe, Emi ko je fi o sile, beni Emi ko je ko o sile.” Matteu 6;24 wip, “ko si eniti o le sin Oluwa meji; nitori yala yio korira okan, yio si fe ekeji; tabi yio faramo okan yio si yan ekeji ni iposi. Sugbon ko le sin Oluwa pelu mammoni.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa tete-tita? Nje tete-tita je ese?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries