settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa eyi?

Idahun


Ni akoko, bi a ba se ri oro ikosile yi si bo se je Pataki to, a ni lati ranti ohun ti Bibeli so fun wa ninu Malaki 2:16: “Nitori Oluwa, Olorun Isreali wipe, on Korira ikosile.” Bi Bibeli ti wi, Ohun ti Oluwa fe ni ki igbeyawo je titi lailai. “ won je meji mon, sugbon okan. Nitori naa ohun ti Olorun ba so sokan, ki enia ki o mase ya won” (Matteu 19:6). Olorun ri wipe, sugbon, nitori pe igbeyawo je ti elese meji, ikosile yio wa. Ninu Majemu Lailai, o si fi ofin sile lori ikosile yi, papa lati fi le ran awon obirin lowo (Deuteronomi 24:1-4). Jesu wipe a fun won ni ofin yi nitori okan lile awon enia, ki se ohun ti Olorun fe (Matteu 19:8).

Ibere nipa boya ikosile tabi ki a fe elomiran ohun ti a ni lati mon geg bi Jesu ti so ni Matteu 5:32 ati 19:9. Gbolohun naa, “afi fun awon alisolododo ninu igbeyawo” e yi ni o je ki Olorun fi ofin naa sile. Awon enia ti o tumo naa si mon eyi ti a ba fi arabinrin fun arakonrin won ko gbodo se ohun ti ko to. Nigba isedale awon Ju, won gbagbo wipe okonrin ati obirin ti se igbeyawo ti won ba ti ma fe ara won. Sugbon ohun agbere ti osele larin won ni o le jasi ikosile.

Sugbon, gbolohun Greki naa “agbere ninu igbeyawo” le je oro miran. O le je pansaga, agbere pelu ife owo, bebe. Jesu n so fun wa wipe ikosile le sele ti agbere ba wa. Ibarasun ninu igbeyawo je ohun ti o se Pataki nitori pe a wipe “Meji yio di okan” (Genesisi 2:24; Matteu 19:5; Efesu 5:31). Nitori naa, eniti o se agbere lati ita igbeyawo le se ikosile. To ba je be, Jesu ti fi han wipe , ikosile ati fife elomiran wa (Matteu 19:9). Eyi si je pe, eni ti ko se ninu igbeyawo naa ni ole fe elomiran sugbon eyi ti o se nilati ba Olorun soro fun idariji ati aun fun ese ti o se ti o ba fe fe elomiran, ni be ge, Bibeli ko so fun wa nipa eyi boya elese naa le fe elomiran.

Awon kan mo 1 Korinti 7:15 gege bi “idasi,” wipe ki a fe elomiran ti alaigbagbo ba ko onigbagbo sile. Sugbon, ko so fun wa nipa, ki a fe elomiran, o so fun wa wipe onigbagbo le fi alaigbagbo sile ti o ba fe ikosile. Awon kan ni pe ko dara, (lati odo oko , aya tabi omo) awon ti o le sele nipa ikosile wa ninu Bibeli sugbon a ko ko papo. Nitori eyi je be, ko si ye ki a se ti Oluwa ko fe.

Bi o ba seje nipa oro agbere ninu igbeyawo, eyi ko nipe ki a se ikosile, bikosepe o ti sele ninu igbeyawo naa. Ti agbere ba wa lari oko ati iyawo, won le bara won soro, dariji ara won ki won sit un igbeyawo won se pelu anu Olorun. Olorun ti darijiwa gaa ni. O si ye ki a se bi Olorun lati dariji ara wa ninu ese agbere (Efesu 4:32). Awon kan si wa ninu igbeyawo naa ti won ko si ni jawo ninu ese naa. A le lo Matteu 19:9. Awon ti won ba si ti se ikosile ma n fe fe elomiran ni kia kia to de je wipe Olorun si fe ki won da duro lati le fi okan won si Olorun (1 Korinti 7:32-35). Ki a fe elomiran le je ohun ti o ku ti ale se sugbon igbamiran Olorun le fe ki a duro nikan.

O se ni ni ironu lati mo wipe ikosile ni arin onigbagbo po bi awon alaigbagbo ni ile aye. Olorun je ki a mo wipe ohun ko fe ikosile (Malaki 2:16) ati wipe, idariji ese ati ilaja ni o ye ki o je igbesi aye onigbagbo (Luku 11:4; Efesu 4:32). Sugbon, Olorun mo wipe ikosile yio sele, ati larin won omo tire. Eni ti won ko sile tabi eni ti o fe elomiran ki o maser o pe Olorun ko feran re, bi o ba ti le je wipe ikosile won tabi fe fe elomiran won ko ba Matteu 19:9 jo. Olorun ma n lo elese aipa ofin re mon lati se ohun rere ni ile aye enia.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa eyi?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries