settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa eya igbeyawo?

Idahun


Iwe Majemu lailai so wipe awon omo Isreali ko gbodo se eya igbeyawo (Deuteronomi 7;3-4).. Idi eyi ni wipe awon omo Isreali yio yi pada leyin Oluwa ti won ba se eya igbeyawo, won yio si sin orisa, tabi keferi. Iwe mimo si so fun wa pe, ti o si fi ye wa: “E ma se fi aidogba dapo pelu awon alaigbagbo: nitori idazo kili ododo ni pelu aisododo? Idazo kini imole si ni pelu okunkun” (2 Korinti 6:14). Gege bi Israelí (igbagbo ninu Olorun otito kan) o si pase wipe a ko gbodo fe alaigbagbo, kristiani (igbagbo ninu Olorun otito kan) o si pase wipe a ko gbodo fe alaigbagbo. Ki a le dahun ibere yi, rara, Bibeli ko so fun wa wipe fife eya ara wa ko dara.

Ise owo eni li a fi n mo eni, ki se ni pa ti awo ara. A ni lati mon wipe a ko gbodo se ayanfe si awon enia kan, tabi ero buburu tabi ti iran (Jakobu 2:1-10, wo ori ese 1 ati 9). Ara kunrin tabi ara birin onigbagbo ti o ba yan ololufe re ni lati mon boya Kristiani ni eni naa (2 Korinti 6:14), e ni ti o baje atunbi nipa igbagbo ninu Jesu Kristi (Johannu 3;3-5). Igbagbo ninu Kristi, ki si nipa eya ara, eyi ni Bibeli so nipa yi yan enikeji re. Igbeyawo eya ara ki se ohun ti o buru tabi ti o dara, sugbon pelu ogbon, akiyesi ati adura.

Idi ti igbeyawo eya fi ni lati j tisora-tisora ni wipe iyonu nipa eya apappo ti yio mu irota ba awon enia lati gba. Awon igbeyawo yi si ma ni iriri iyanju ati eleya, nigba miran lati odo ebi won. Awon elomiran si ma ni irora naa, nigbati omo won ba yato si ebi ti won ti wa nitori ella ara won. Eyi je pataki nigbati a ba fe lo sinu igbeyawo eya. Lekeji, biotilejepe, eyi ti Bibeli so nipala nipa eni ti omo lehin Kristi le fe ibase elomiran si ni eya ara Kristi.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa eya igbeyawo?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries