settings icon
share icon
Ibeere

Kini pataki irubomi Kristiani?

Idahun


Irubomi Kristiani, gege bi Bibeli, eyi je ohun eri isiha ti o sele ninu aye Olugbagbo. Eyi fi han wipe a ti ku pelu Kristi, lo isa oku ati tun jinde. Bibeli wipe, tabi e ko mo pe, gbogbo wa ti a ti baptisi sinu Kristi Jesu, a ti baptisi wa sinu iku re? Nje a fi baptisimu sinu iku sin wa po pelu re; pe gege bi a ti ji Kristi dide kuro ninu oku nipa ogo Baba beni ki awa pelu ki o ma rin li otun iwa (Romu 6;3-4). Ninu irubomi Kristiani, eyii ti a ri yin boo mi fi han wipe a ku pelu Kristi. O si fihan wipe nigbati a jade ninu omi naa a si jinde pelu Kristi.

Ni irubomi Kristiani, ohun meji ni o ni lati se ki a to se irubomi (1) eni ti o n se irubomi naa lati gbagbo ninu Jesu Kristi gege bi Olugbala ati (2) o si ni lati mo itumo irubomi. Ti eni naa ba won Olorun Jesu gege bi Olugbala, ti o mon wipe irubomi Kristiani je igbese ofin ni gbangba lati ni igbagbo ninu Kristi, o si fe se irubomi- ko si si ohun ti o ye ki o da onigbagbo naa duro lati se irubomi. Gege bi Bibeli, irubomi Kristiani je igbese ofin, eyi ti a fi so ni gbangba nipa igbagbo ninu Kristi nikan fun igbala. Eyi je ofin naa- ki a si so wipe igbagbo wa ninu Kristi a si ti fi gbogbo re le lowo, ti a si ti jeri iku Kristi, ibi iku re ati ajinde re.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini pataki irubomi Kristiani?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries