settings icon
share icon
Ibeere

Kini yio sele lehin iku?

Idahun


Ibere nipa kini yio sele leyin iku je gege bi ohun ti o ru ni ni oju. Bibeli ko so fun wa igba ti enia yio de ipari aye re. A si mo wipe, Bibeli so fun pe lehin ti enia ba ku yio lo si paradise tabi orun apadi boya eni naa ti gba Jesu gbo tabi rara. Nipa omo Olorun, a mo wipe ti won ba ku, ara won ko ni si mon sugbon won yio wa pelu Olorun (2 Korinti 5:6-8; filippi 1:23). Fun awon keferi, leyin iku, iya ayeraye ninu orun apadi (Luku 16:22-23).

Eyi ni o je eyi ti o ru wa loja nipa kini yio sele leyin iku. Ifihan 20:11-15 so fun wa wipe gbogbo awon ti o ba wa ni orun apadi yio lo si iho ina. Ifihan ori 21-22 so nipa orun titun ati aye titun. Nitori naa, titi di igba ajinde, leyin iku, enia yio wa ni arin orun ati apadi. Ko si bi ohun ti Oluwa ti pinu se le yipada, sugbon ibi ti enia yio lo si le yipada. Leyin iku, won yio si so awon keferi si inu ina apadi (Ifihan 20:11-15). Eyi ni opin, ohun ti o si ti wa fu nomo enia- nipa ti enia ba ti gba Jesu Kristi gege bi olugbala ese re.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini yio sele lehin iku?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries