settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa Metalokan?

Idahun


Ohun ti o nira nipa igbagbo ninu metalokan bi Kristiani se mo si ni a ko le so. Metalokan niran fun omo enia lati le ni oye patapata nipa re. Olorun to bi ju wa lo, nitori naa a ko le mo ni kikun tan. Bibeli ko wa pe, Baba ni Olorun, wipe Jesu ni Olorun, Emi Mimo naa si je Olorun. Bibeli si tun ko w ape Olorun kan lowa. Sugbon a le mon bi awon omiran se je ti Metalokan, be naa, o le lati ye ni. Sugbon eyi ko so wipe ki se otito tabi pe Bibeli n paro.

Fi sokan wipe igba ti a ba n ko eko yi iwe mimo o daruko Metalokan. Ohun ti won fi salaye fun wa naa niyi, awon meta ni owa, eyi ti o wa ni ita to je gege bi Olorun. A ko so wipe Olorun meta lo wa. Metalokan je okan, Olorun ni ona meta. Ko si ohun ti o buru lati lo “Metalokan” sugbon won ko lo ninu Bibeli. O dara ti a ba wipe Metalokan ju ki a ni wipe meta lo wa laye. Ti eyi ba je iloju fun o, wo eyi; a ko lo baba baba mi ninu Bibeli. Sugbon a mon wipe a ni won ninu Bibeli. Abrahamu je baba baba Jakobu. Nitori be ni oye ti “Metalokan.” Ohun ti o ye ki a mo ni wipe, ohun ti a lo lati FI-HAN nipa “Metalokan” wa ninu iwe Mimo naa. Ni gbati a si ti so eyi, eje ki awo ni dardara.

1) Olorun kan ni o wa: Deuteronomi 6:4; 1 Korinti 8:4; Galatia 3:20; 1 Timoteu 2:5.

2) Metalokan je enia meta: Genesis 1:1; 1:26; 3:22; 11:7; Isaiah 6:8; 48:16; 61:1; Matteu 3:16-17; Matteu 28:19; 2 Korinti 13:14. Ninu iwe Majemu Lailai, oye Heberu ran wa lowo. Ni Genesisi 1:1, eyi ti o ju imi lo “Elohim” a lo. Ni Genesisi 1:26; 3:22; 11:7 ati Isaiah 6:8, a lo oro ti a fi dipo oruko, “awa.” Eyi ti o je Elohim ati awa fi ye w ape won ju meji lo LAI NI ibere. Ninu ede oyinbo, meji ni a ni, okan ati pupo. Ni ti Heberu, meta ni ani; okan, meji ati eyi ti o ju meji. Meji yi si meji NIKAN. Ninu Heberu, eji ni an lo fun ohun ti o wa bi mejimeji oju, eti, ati owo. “Elohim” ati “awa” ju pupo- ti o je meji lo- ti o si le je meta tabi ju be lo (Baba, Omo, Emi Mimo).

Ninu Isaiah 48:16 ati 61:1, Omo n soro nipa Baba ati Emi Mimo. Wo Isaiah 61:1 ati Luku 4:14-19 lati mo wipe Omo ni o n soro. Matteu 3:16-17 soro nipa ohun ti o sele si Irubomi Jesu. Eyi fi han wipe Baba ati Emi Mimo wa si ori Olorun ti oje Omo naa, ti o si je wipe Olorun Baba si so ohun ti o wa ni okan re nipa Omo re. Matteu 28:19 ati 2 Korinti 13:14 je gege bi apere enia meta ninu Metalokan.

3) Eya ara eyi ti je Metalokan wa ninu eyi ti a o so. Ninu iwe Majemu Lailai,“OLORUN yato si “Olorun” (Genesisi 19:24; Hosea 1:4). “OLORUN ni “Omo” (Orin Dafidi 2:7, 12; Owe 30:2-4). Emi si yato “OLORUN” (Numeri 27:18) ati ti “Olorun” (Orin Dafidi 51:10-12). Olorun ti Omo yato si Olorun Baba (Orin Dafidi 45: 6-7; Heberu 1:8-9). Ninu iwe Majemu Titun, Johannu 14:16-17 Jesu si wi fun Baba re wipe ki o ran Oluranlowo wa, ti Emi Mimo. Eyi fi han wipe Jesu ko so wipe ohun ni Baba tabi Emi Mimo. Ki o sit un wo gbogbo igba ti Jesu fi ba Baba re soro. Nje o n ba ara re wi? O ba elomiran soro lara Metalokan- Baba.

4) Eya ara Metalokan ni Olorun: Baba ni Olorun: Johannu 6:27; Romu 1:7; 1 Peteru 1:2. Omo na si je Olorun: Johannu 1:1, 14; Romu 9:5; Kolosse 2:9 ; Heberu 1:8; 1 Johannu 5:20. Emi Mimo si ni Olorun: Ise Awon Aposteli 5:3-4; 1 Korinti 3: 16 ( Eyi ti o n gbe inu ni Emi Mimo-Romu 8:9; Johannu 14:16-17; Ise Awon Aposteli 2:1-4).

5) Iwalabe metalokan naa ni: iwe Mimo sofun wa pe Emi Mimo je omo leyin Baba ati Omo, Omo si je Omo leyin Baba. Eyi je asepo, ko si si ohun ti o ya won pelu ise ti olukaluku nse. Eyi fi han wipe a ko le ni oye gbogbo bi Olorun se je. Nipa ti Omo wo: Luku 22:42; Johannu 5:36; Johannu 20:21; 1 Johannu 4:14. Nipa ti Emi Mimo wo: Johannu 14:16; 14:26; 15:26; 16:7 ati papa Johannu 16:13-14.

6) Ise onikaluku yato: Baba ni Ipinlese gbogbo re: 1) Agbaye (1 Korinti 8:6; Ifihan 4: 11); 2) Ifihan ti Olorun (Ifihan 1:1); 3) Igbala (Johannu 3:16-17) Ise Jesu (Johannu 5:17; 14:10). Baba ni o bere gbogbo eyi.

Omo je omo leyin, eyi ti Baba fi n se ise re: 1) Agbaye ati ise ti o n se ni Gbogbo aye (1 Korinti 8:6; Johannu 1:3; Kolosse 1:16-17); 2) Ifihan Ise re (Johannu 1:1; Matteu 11:27; Johannu 16:12-15; Ifihan 1:1); ati 3) Igbala (2 Korinti 5:19; Matteu 1:21; Johannu 4:42). Baba n se gbogbo ise yi nipa Omo re, ti o je oluranlowo.

Emi Mimo je ona ti Baba n gba lati se isere: 1) ohun ti o da ati itoju agbaye (Genesisi 1:2; Jobu 26:13; Orin Dafidi 104:30) ; 2) Ifihan ise re (Johannu 16:12-15; Efesu 3:5; 2 Peteru 1:21); 3) Igbala (Johannu 3:6; Titu 3:5; 1 Peteru 1:2); ati 4) Ise Jesu ( Isaiah 61:1; Ise Awon Aposteli 10:38). Baba n se gbogbo ise yi nipa agbara Emi Mimo.

Ko si eyi ti a lo lati fi salaye ti o se dede nipa Metalokan. Ti Eyin ( tabi eso) ba baje ninu ikarahun re, ti fifun re, ti pupa re, nkan naa si ni won ki se eyin ninu wara won. Baba, Omo, Emi Mimo, won ko wa pelu Olorun, ikan kan ninu wo je Olorun. Eyi ti a fi se apere nipa omi dara sugbon ko le fun wa ni itumo Metalokan. Sisan, oru, omi didi je ti omi. Baba, Omo ati Emi Mimo won je geg bi Olorun, Olorun ni okan kan won. Nitori naa, ti eyi fi le han wa nipa Metalokan, o si le ru wa loju die. A ko le so itumo Olorun ti ko ni opin pelu bi a se so. Mase fi okan tabi emi si Metalokan sugbon fi oju re Olorun Oba ti oni agbara ti o sig a ju gbogbo nkan aye yi lo. “A! ijinle oro ati ogbon ati imo Olorun! Awamaridi idajo re ti ri, ona re si ju awari lo! Nitori tali o mo inu Oluwa? Tabi tani ise igbimo re?” (Romu 11:33-34).

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa Metalokan?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries