settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa idamewa Kristiani?

Idahun


Idamewa je ohun ti kristiani tiraka latise. Ni ijo miran. Idamewa je itenumo. Fun eyi, awon kristiani o fe se Olorun wa nipa didawo. Idamewa / fifun je ohun ayo ibukun. Pelu re naa, eyi ko je be naa ni ijo toni.

Idamewa je ti Majemu Lailai. Eyi je ofin wipe gbogbo omo isreali lati da idamewa ninu ohun ti won ba ri tabi ti won gbin ninu Tempili (Lefitiku 27:30; Numeri 18:26; Deuteronomi 14:24; 2 Krronika 31:5). Awon kan ni oye Majemu Lailai ti idamewa geg bi owo- ode fun awon ara Alufa ati Lefi fun ebo. Iwe Majemu Titun si wi fun wa wipe ki ase irubomi eyi. Paulu wipe ki awa onigagbo yo idamewa wa si oto lati ran ile ijo ni owo (1 Korinti 16:1-2).

Iwe Majemu Titun ko so fun wa oye ti o ye ki fi sile, sugbon o wipe ki “ki o wa pelu ere” (1 Korinti 16:2). Awon Kristiani ni o mu idamewa (10%) wa lati inu Majemu Lailai ti won si fi mule wipe “file eyi to kere ju” fun kristiani lati fi sile. Sugbon iwe Majemu titun o so fun wa nipa oye ti o ye ki fissile,sugbon o soro nipa dida owo naa “bi a se le da gege bi ere wa.” Nigbamiran eyi je dida idamewa wa ti a ba le da ju eyi lo, tabi ti o ba kere ju ere idamewa lo. Bi eni naa ba se da ati ohu ti ile ijo fe. Gbogbo kristiani ni o ni lati gba adura fun oye lati mo bi ohun se le da owo naa ( Jakobu 1:5). “Ki olukuluku eniaki o se gege bi o ti pinnu li okan re; ki ise afekunse, tabi ti alaigbodo ma se; nitori Olorun fe oninudidun olore” (1 Korinti 9:7).

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa idamewa Kristiani?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries