settings icon
share icon
Ibeere

Nje igbala ayeraye wa ninu Bibeli?

Idahun


Nigbati awon enia ba mon Kristi gege bi olugbala won, won yio si sun mon Olorun ti yi o si fun won ni igbala ayeraye. Juda 24 so wipe, “Nje ti eniti o le pa nyin mo kuro ninu ikose, ti o si le mu nyin wa siwaju ogo re lailabuku pelu ayo nla.” Agbara Olorun le gba wa ki a si ma kose. O ni o le se ohun ti o ba fe se, ki se awa, ki a si wa ni ona ogo ni waju re. Igbala ayeraye wa ni Oluwa ti o n toju wa, ki se nipa igbala ara wa.

Jesu Kristi Oluwa wipe, “Emi si fun won ni iye ainipekun: nwon ki o si segbe lailai, ko si si eniti o le ja won kuro li owo mi. Baba mi, eniti o fi won fun mi, po ju gbogbo won lo: ko si si eniti o le ja won kuro li owo Baba mi (Johannu 10;28-29). Jesu ati Baba wa si ti mu wa duro sinsin ni owo won. Tani o le ya kuro ninu owo Baba ati omo re?

Efesu 4:30 wipe, “eniti a fi se edidi nyin de ojo idande.” Ti onigbagbo o ba ni igbala ayeraye, edidi naa ki yio je idande ayeraye, sugbon titi de ona elese tabi aigbagbo. Johannu 3:15-16 so fun wa wipe eni ti o ba gbagbo ninu Jesu Kristi “yio ni igbesi ayeraye.” Ti a ba ni pe a o fun enia ni igbesi ayeraye, sugbon agba lowo re, Eyi ki se “igbesi ayeraye” ti a ba so. Ti igbala ayeraye o ba otito, eyi ti Bibeli so nipa re yio si je iro.

Eyi ti awon enia n jiyan re nipa igbala ayeraye si wa ninu Romu 8:38-39, “Nitori o da mi Loja pe, ki ise iku, tabi iye, tabi awon angeli, tabi awon ijoye, tabi awon alagbara, tabi ohun igba isisiyi, tabi ohun igba ti mbo. Tabi oke, tabi ogbun, tabi eda miran kan ni yio le ya wa kuro ninu ife Olorun, ti o wa ninu Kristi Jesu Oluwa wa.” Igbala ayeraye wa fun wa gege bi ife Olorun fun awon ti o ti ni ndande. Igbala ayeraye wa wa nipa ti Kristi, nipa ti Baba, ti o si yi wa ka pelu Emi Mimo.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Nje igbala ayeraye wa ninu Bibeli?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries