settings icon
share icon
Ibeere

Kini Bibeli so nipa eyi? Nje eyi je ese?

Idahun


Bibeli so fun wa wipe ibalopo pelu eda kan naa je ese (Genesisi 19:1-13); Levitiku 18;22: Romu 1:26-27; 1 Korinti 6:9). Romu 1:26-27 ko wa wipe ibasepo pelu eda kan naa je wipe bi aigboran ki a si ma tele ofin re Olorun. Ti enia wa ninu ese ati aigbagbo, Bibeli so fun wa wipe Olorun si “ Ki a si ko sile” ki a ma tele iru ona biburu yi nitori pe ko pe. 1 Korinti 6:9 wipe Ibasepo pelu eda kan naa “Elese“ ki yio je ere Olorun.

Olorun o da enia pelu iru iwa yi. Bibeli so fun wa wipe enia bere iwa kiwa yi nitori ese (Romu 1:24-27), ati wipe ohun ti won fe niyen. Won le bi eniyan ki o si ma ro wipe ohun ni iru emi yi lati ma ba eda kan naa lo po, bi awon kan ti wa ti o je wipe won ti bi won pelu ese ati ija. Ko si ye kiwon tele ese yi. Eni ti won ba bi pelu emi yi, won ko ye ki won tele ona naa. Rara! Bena ni iwa ibanisepo pelu eda kan naa.

Gege bee naa, Bibeli o ni wipe iwa yi je eyi ti o ju ese miran lo. Gbogbo ese ni o lodi si Olorun. Ibasepo eda kan naa je ikan lara ohun ti Oluwa o feran ti o wa ninu 1 Korinti 6:9-10 ti yio si je ki a sina ile orun Oluwa. Gege bi Bibeli, idariji ese wa fun gbogbo enia bi ese re ba se je. Oluwa si wipe ohun yio fun wa ni okun ati agbara lori ese, pelu ibasepo pelu eda kan naa, fun awon ti o ba gbagbo ninu Jesu Kristi fun igbala won (1 Korinti 6:11; 2 Korinti 5:17).

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Bibeli so nipa eyi? Nje eyi je ese?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries