Àwọn ìbéèrè nípa Ẹgbẹ́ òkùnkùn àti Ẹ̀sìnEsin wo lo to si mi?

Kínni ìtumọ̀ ẹgbẹ́ òkùnkùn?

Kínni ọ̀nà tí ó dára jùlọ láti wàásù fún ẹnìkan tí ó ńbẹ nínú ẹgbẹ́ òkùnkùn tàbí ẹ̀sìn èké?

Báwo ni mo ṣe lè dá olùkọ́ èké/wòlíì èké mọ̀?

Báwo ni mo ṣe lè yípadà sí ẹ̀sìn Kristiẹni?

Kínni ẹ̀sìn tòótọ́?

Àwọn wo ni Ajẹ́rìí Jèhófa àti kínni wọ́n gbágbọ̀?

Ǹjẹ́ Ṣíṣe Mọ́mọ́nì jẹ́ ẹgbẹ́ òkùnkùn kan? Kínni àwọn Mọ́mọ́nì gbàgbọ́?

Kínni ìwò Kristiẹni nípa àwọn aríran?

Ṣé ó yẹ kí Kristiẹni máa ní sùúrù nípa ìgbàgbọ ẹsín ti ẹlòmíràn?

Ṣé ẹ̀kọ́ nípa ìgbàlà gbogbo àgbáyé/ìgbàlà ti gbogbo àgbáye bá Bíbélì mu?


Àwọn ìbéèrè nípa Ẹgbẹ́ òkùnkùn àti Ẹ̀sìn