settings icon
share icon
Ibeere

Esin wo lo to si mi?

Idahun


A le ra onje ni buka bi a ba se fe si. Awon ibi ti won n ta onje ma n ni ogorun orisirisi onje. Tabi ti aba fe ra ile tabi oko, o pe orisirisi, eyi to ba wu wa ni a le ra. A gbe ninu ile aye ti o dun fun eroja didun. Ohun ti a fe ni Oba! O le ri ohun ti o ba fe gege bi a ba se fe si ati ni li lo re.

Sugbon bawo ni esin ti to si o? Ba wo ni esin ti ko nira, ti ko bere fun ohun ko ohun, ti ko si ni ohun ti o le nipa ohun ti o ye ko se ati eyi ti ko ye? O nbe, bi mo se so, sugbon se esin je gege bi ohun orisirisi si bi onje ti a feran lati je?

Opolopo ekun ni o n ke fun, ki ni o de ti a ma se fi li gbe elomiran ga ju Jesu lo, bi Mohamedi tabi Konfuciusi, Buda, Charles Taze Russell, tabi Joseph Smith? Abi naa, se lai se gbogbo ona lo lo si orun? Se ki se gbogbo esin lo je ba kan naa? O to ni wipe, ki se gbogbo esin ni o ja si orun, bi gbogbo ona naa ko ja si Indiana.

Jesu nikan soro pelu ase Olorun nitoripe Jesu nikan ni oni igbala lori iku. Mohamedi, konfuciusi ati awon to ku wa ninu isa oku titi di isin yi, sugbon Jesu, pelu agbara re, rin jade lati inu ibodi lehin ojo meta nigbati won kan mo igi agbelebu awon Romu. Enikeni to ba ni agbara lori oku je eni ti a ni lati mo nipa. Enikeni ti o ba ni agbara lori o ko je eni ti a ni lati gbo ni pare.

O o to ti o nipan ti o je ki a mon nipa ajinde oluwa o se ni ni iyanu. Ikuni awon eniyan bi egbedogbon ni ori Kristi jinde. Opolopo eniyan ni yen. Ohun awon enia egbedogbon ko le je ohun ti a le gbagbe. Inu ibodi ti o o si sofo je ikan miran; awon ota Jesu, won ko le da awon eniyan dajke nipa ajinde re nitori pe, won ko le fi ori re han, ara re re ti o ke, sugbon ko si ara re ni? Rara. Ki a ma se ni iro naa, won si fi awon ologun si enu ibode Jesu. Kiyesi, awon omo lehin re ti o sunmo sa lo, won beru nigba ti a mu, ti a si kan mo n igi, nitori eyi, ko si ibi awon omo leyin re ti won je oniberu apeja se le ni agbara lati ba awon ologun ja. Ni soki a ko le so wipe ki a gbagbe nipa ajinde, ajinde jesu.

Nibayi, enikeni ti o ba ni agbara lori oku ni lati je eni ti a ni lati gbo nipa. Jesu fi agbara re han lori oku, nitori naa, o ye ki a mo ohun ti o n so. Jesu nikan ni ona iye (Johannu 14;6). Ki se ona, ki se eni ona pupo, sugbon Jesu naa ni ona.

Jesu yi naa so wipe, “E wa sodo mi gbogbo eyin ti nsise ti asi di eru wiwo le lori, emi o si fi isimi fun nyin. (Matteu 11;28). Ile aye yi le gan o si kan. A ti ri iri aye, iya, iya orisirisi. Ma se jiyan? Ki ni o fe? Iso ni di igba tabi ebo to sofo? Jesu ko ni yiyan-Ohun si ni yiyan.

Jesu ni ododo “esin” ti o ba n wa idariji ese (Ise Awon Aposteli 10;43). Jesu ni “esin” naa ti o ba n fe idani loju ododo pelu Oluwa (Johannu 10;10). Jesu ni esin naa ti iwo ba fe iye ainipekun ni ile paradise (Johannu 3;16). Fi Igbagbo re le Jesu Kristi olugbala- o si ni segbe! Ni ireti ninu idariji ese re- iwo ki yi o padanu aye re.

Ti iwo ba fe ni igbesi “olododo” ninu ola Oluwa, eyi ni adura ni soki. Ranti wipe, gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re. “Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Esin wo lo to si mi?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries