Àwọn ìbéèrè nípa ÀdúràKílódé tí a fí ńgbàdúrà? Kínní kókó tí a fí ńgbàdúrà nígbatí Ọlọ́run ti mọ ọjọ́ iwájú tí ó sì ti wà náà ní ṣíṣe àkoso ohun gbogbo. Bí a kò bá lè yí ọkàn Ọlọ́run padà, kílodé tí àwa fi gbọ́dọ̀ gbàdúrà?

Kínni àdúrà Olúwa àti wípé ṣe ó yẹ kí a gbàá?

Kínni o túmọ̀ sí láti gbàdúrà l’órúkọ Jésù?

Báwo ni mo ṣe lè jẹ́ kí Ọlọ́run dáhùn àdúrà mi?

Ǹjẹ́ àdúrà àjùmọ̀gbàpọ̀ ṣe pàtàkì? Ǹjẹ́ àdúrà àjùmọ̀gbàpọ̀ àdúrà lágbára ju àdúrà àdáníkangbà lọ?

Ǹjẹ́ o ṣe ìtẹ́wọ́gbà láti tún àdúrà gbà fún nǹkan kańnáà?


Àwọn ìbéèrè nípa Àdúrà