Àwọn ìbéèrè nípa BíbélìNje Bibeli je oro Olorun ni toto?

Báwo àti nígbàwo ni a ṣe àkójọpọ̀ Bíbélì?

Ṣé Bíbélì ní àwọn àṣìṣe, àwọn ohun tí ó takò ra wọn, tàbí àwọn ohun tí ó yàtọ̀ sí ra wọn?

Kínni ó túmọ̀ sí wípé Bíbélì ní ìmísí?

Ṣé Bíbélì wúlò lóòní?

Kínni ìdí tí a fi gbọ́dọ̀ ka Bíbélì/kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Kínni ọ̀nà tí ó tọ́ láti k'ẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?


Àwọn ìbéèrè nípa Bíbélì