Àwọn ìbéèrè nípa Ìṣẹ̀dáKínni Bíbélì sọ nípa ìṣẹ̀dá àti ẹfolúṣàn?

Kínni ọjọ́ orí ayé? Báwo ni ayé ṣe dàgbà tó?

Ṣé ìkún omi Nóà jẹ́ àgbáyé tàbí àgbègbè?

Kínni Àbá Iṣẹ́ àkànṣe Tí ó mọ́pọlọ dání?

Ǹjẹ́ ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run àti ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ sáyẹ̀nsì tako ara wọn bí?

Kílódé tí Ọlọ́run fifi igi ìmọ̀ rere àti búburú sínú ọgbà Édẹ́nì?

Kini Bibeli so nipa eranko bi alangba yi? Nje eranko nla atijo yi wa ninu Bibeli?

Tani iyawo Kaini? Nje iyawo Kaini je gege bi aburo re?


Àwọn ìbéèrè nípa Ìṣẹ̀dá