settings icon
share icon
Ibeere

Bawo ni mo sele mo ti ohun ti Oluwa fe fun mi? Kini Bibeli so nipa mimo ohun ti Oluwa fe?

Idahun


Ona meji ni a fi le mo ohun ti Oluwa fe (1) mo wipe ohun ti iwo n se tabi ti o n ro ko gbodo lodi si iwe Bibeli. (2) Mo wipe ohun ti o ba n bere fun tabi ti o n se lati gbe ogo Olorun ga ninu emi. Nje ti n kan meji yi ba je otito, ti Olorun ko si da e lohun- lehin naa, eyi o fi ye o wipe ohun ti o hun bere fun ki se ohun ti Oluwa fe. Tabi iwo yio si duro die latir i gba. Lati mo ona Oluwa ma n je ohun ti o le. Awon enia fe je ki Oluwa so fun won nipa ohun ti won ye ki won se- Ibi ti won ti ye ki won sise, ibi ibugbe, eni ti won ye ki won fe, ati bebe. Romu 12;2 so wipe, ‘ki e ma si da ara nyin po mo aiye yi; sugbon ki e parada lati di titun ni iro-inu nyin. Igba yen ni iwo yio mo ohun ti Oluwa fe- Ohun daradara re, ona toto ati ileri re.

Oluwa ko kin fi ise re han ni gba n gba. Oluwa ma n fe ki a se ohun ti a ba fe. Ohun kan ti Oluwa ko fe ka se ni wipe, ki a gbin moran lati da ese tabi ka rin ona miran. Oluwa fe ji a se ohun ti a ba fe ni ona otito re, Bawo ni mo sele mo ohun ti Oluwa fe fun mi? Ti iwo ba n tele Oluwa ti o si mo ona re- Oluwa yi o si fun o ni ohun ti o ba fe (Orin Dafidi 37;4). Ti Bibeli ko ba jiyan re, ti o si le ran o lowo nipa ti emi- Bibeli si fun ni aye naa lati se ohun ti o fe ki o si tele ohun ti okan re so.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Bawo ni mo sele mo ti ohun ti Oluwa fe fun mi? Kini Bibeli so nipa mimo ohun ti Oluwa fe?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries