settings icon
share icon
Ibeere

Ba wo ni mo sele mo wipe emi yi o los i orun nigbati mo ba ku?

Idahun


Se iwo mo wipe oni iye ainipekun ati wipe iwo yi o si orun ti o ba ku? Oluwa fe ki o mo! Bibeli wipe: “Nkan wonyi ni mo ko iwe re sin yin ani si enyin ti o gba Oruko omo Olorun gbo, ki enyin ki o le mo pee yin ni iye ainipekun” (1 Johannu 5; 13). Sugbon ti iwo ba duro niwa ju Oluwa ni sin yi ti o si bere lowo re, ‘fun mi ni idi ti mo fi je ko wo orun? Kini iwo yio so? O le maa mo n ohun ti o so. O ni lati mo wipe Oluwa ni ife wa, o si ti pese ibi ti awa yi o ti gbe igbesi aye wa titi lai lai. Bibeli so wipe, “Nitori Olorun fe araiye to be ge, ti o fi omo bibi re kansoso fuuni ki enikeni ti o ba gba a gbo ma ba segbe sugbon ki o le ni iye ainipekun” (Johannu 3; 16).

A ni lati koko mo whahala ti ko ni je ka de orun. Awon whahala naa niyi- Ese wa ko le je ka je olododo ninu Oluwa. Elese ni awa la ti ibere ati ohun ti a fe. “Gbogbo enia li o sa ti se, tin won si kuna ogo Olorun (Romu 3; 23). A ko le gba ara wa la. “Nitori ore-ofe li a ti fi gba nyin la nipa igbagbo; ati eyini ki ise tie yin tikaranyin; ebun olorun ni- ki ise nipa ise, ki enikeni ma ba sogo” (Efesu 2;8-9). Ohun to to si wa ni iku ninu orun apadi. “Nitori iku ni ere ese” (Romu 6:23).

Mimo ni oluwa ati olu dande o si ni lati fiya je ese, sugbon o ni fe wa, o si pese idariji fun ese wa. Jesu wipe, “Emi li ona, ati otito, ati iye, ko si enikeni ti o le wa sodo Baba bi ko se nipase mi” (Johannu 14;6). Jesu ku fun wa lori igi agbelebu; “Nitori ti Kristi ese wa dopin, nitori ese wa oloto ku fun awon alaisoto, ki o le mu wa de odo Olorun” ( 1 Peeteru 3;18). Oluwa jinde ninu isa oju; “Eni ti a fi tore fun ese wa, ti o si jinde nitori idalare wa” (Romu 4;25).

Nitori naa, e je ki a pada si ibere wa- Ba wo ni mo se le mo wipe emi yi o lo si orun nigbati mo ba ku? Idahun naa niyi- Ni igbagbo ninu Olorun Jesu Kristi, iwo yi o si ni igbala (Ise Awon Aposteli 16;31). “Sugbon iye awon ti o ba gba a, awon li o fi agbara fu lati di omo Olorun, a ni awon na ti o gba oruko re gbo (Johannu 1;12). Iwo le gbe iye ainipekun fun OFE! “Sugbon ebun ofe Olorun ni iye ti ko nipekun ninu Jesu Kristi Oluwa wa (Romu 6;3 ). Iwo le gbe igbesi aye to dara. Jesu wipe, “Emi wa kin won le ni iye, ani kin nwon le ni lopolopo (Johannu 10;10). “Ti emi ba de lo, emi n lo lati lo pese aye sile fun yin, emi o tun pada wa, emi o si mu nyin lo sodo emi tikarami; pe nibiti emi gbe wa, ki eyin le wa nibe pelu” (Johannu 14;3).

Ti iwo ba fe gba Jesu Kristi gege bi olugbala re, ki o si ni idariji ese lowo re, eyi ni adura ti o legba. Gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re.“ Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun anu ati idariji ese mi! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ba wo ni mo sele mo wipe emi yi o los i orun nigbati mo ba ku?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries