settings icon
share icon
Ibeere

Mo sese fi igbagbo mi sinu Jesu ... Leyin naa?

Idahun


Mo sese fi igbagbo mi sinu Jesu ... Leyin naa?"

Oku ori re! O ti se ipinu ti yio tun aye re se titi laye. O le ma ber wipe, “Leyin eyi n ko? Ba wo ni mo se le ber irin ajo mi pelu Olorun?” igbe se marun ti a daru ko ni isale yi yio fun e ni oye lati inu Bibeli. To o ba ni awon ibere ni irin ajo yi, dakun lo si www.GotQuestions.org/Yoruba.

1. O se pataki ki o mo oye irapada yi.

1 Johanu 5:13 so wipe, mo ko si yin eyin ti e nigbagbo ninu omo Olorun ki e file mo n wipe eyin ni iye ainipekun. “Oluwa fe ka mo nipa igbala. Oluwa fe ka ni idani loju mimo yeke yeke pe a ti di atubi. Ni soki, fe ka lo si awon oro to se koko nipa ira pada.

(a) Gbogbo enia li o sa ti se, gbogbo enia ni won ti kuna ogo Olorun (Romu 3:23)

(b) Nitori ese wa, o ye ki a je iya ayeraye fun ipinya ayeraye pelu Olorun (Romu 6:23)

(c) Jesu ku fun walori agbelebu lati ra wapada ninu ese wa (Romu 5:8; 2 Korinti 5:21) Jesu ku fun wa, o si gbe iya ti o yewa. Ajinde re si fihan wipe iku Jesu to lati rawa pada lowo ese.

(d) Oluwa fun wa ni idariji ese ati igbala fun gbogbo awon ti o ba fi igbagbo re le Jesu lowo- Ni iku re nipa irapada ese wa (Johannu 3:16; Romu 5:1; Romu 8:1)

Eyi ni oro irapada! Ti o ba ti fi igbabgo re si inu Jesu Kristi fun irapada, o ti di eni atubi! Idariji ti wa fun gbogbo ese re, Oluwa si nip e ohun o ni fi o si le tabi ko e sile (Romu 8:38-39; Marku 28:20). Ranti, igbala re wa lowo Jesu Kristi (Johannu 10:28-29). Ti iwo ba ni ireti ninu Jesu ni kan to je olugbala, ni ida ni loju wipe iwo yi o gbe iye ainipekun pelu Oluwa ni paradise.

2. Wa ile ijosin ti o n ko Bibeli dada

Ma se wo ile ijosin bi ile ti a gbeduro. Ile ijosin ni enia. O se pataaki pe awon to gbagbo ninu Jesu Kristi josin larin ara won. Eyi je ikan ninu ohun pataki ijo. Lehin ti o ti ni igbagbo ninu Jesu Kristi, a gba ni imoran gidigidi pe ki o wa ile ijosin Bibeli gidi ni agbegbe re ki o sib a Oluso agutan soro. Je kio mon nipa igbagbo re ninu Jesu Kristi.

Ohun pataki ile ijosin keji ni wipe, o ni lati ko nipa. Wa mon bi o se le gbe igbese Oluwa ninu ayeraye. Oye Bibeli je gege bi ohun a ase yo ri fun gbigbe igbese aye ati agbara fun omo lehin Jesu. 2 Timoteu 3:16-17 wipe, “Gbogbo iwe-mimo ti o ni imisi Olorun li o si ni ere fun eko, fun ibani-wi, fun itoni, fun ikoni ti o wa ninu ododo. Ki enia. Olorun ki o le le pe, ti a ti mura sile papata fun ise rere gbogbo.

Ohun pataki keta ni wipe ile ijosin ni lati ma yin Oluwa. Yiyin Oluwa tumo si ope lowo Oluwa fun gbogbo ohun ti o ti se! Oluwa ti raw a pada. Oluwa ni ife wa. Oluwa pese fun wa. Oluwa fi wa mona osi fi ona han wa. Bawo ni ase ni dupe lowo re? Mimo ni oluwa, Olododo, ife, alanu, alabukun. Ifihan 4:11 wipe, ‘Oluwa, iwo li o ye lati gba ogo ati ola ati agbara: nitoripe iwo li o da ohun gbogbo, ati nitori ife inu re ni nwon fi wa si da won.

3. Fi aye sile ni ojo gbogbo lati ba Oluwa soro

O se pataki fun wa lati ba Oluwa soro ni ojo jumon. E lomi ran le pe ni idakeroro. A tun le pe ni nitoripe eyi ni asiko ti a fi gbogbo igbesi aye wa fun Oluwa. E lo miran si ma a n fi asiko sile ni aro nigbati elo miran feran irole. Ko si ohun to yato bi o ba je asiko yi tabi igbakigba. Ohun to se pataki ni wipe nigba gbogbo a ni lati ma ba oluwa soro. Iru awon igbese wo ni o fe asiko Oluwa?

(a) Adura. Bi ba Oluwa soro ni adura. Ba Oluwa soro nipa ohun to n du o ninu. So fun oluwa bi o se ni ife re ati bi o se iyanu ninu aye re. Eyi ni adura.

(b) Bibeli kika. Fun ipapo Bibeli kiko ni ile ijosin, ile eko ojo isinmi, tabi eko Bibeli – o ni lati ma ka Bibeli fun arare. Bibeli ni gbogbo ohun ti o ni lati mo fun ohun aseyori omo Olorun. O ni igbese oluwa lati gbe igbese gidi, lati mo ohun ti oluwa fe fun wa, lati le ba enikeji wa soro, ati lati le rin irin ajo idagba si ninu emi. Bibeli ni oro Oluwa fun wa. Bibeli je ohun pataki igbese oluwa lati le gbe aye wa ni ona to to si oluwa ati awa naa.

4. Gbiyanju lati ke gbe po pelu awon eniyan ti yio mu e dagba ninu emi.

1 Korinti 15:33 so wipe, “ki a ma tan nyin je; egbe buburu ba iwa rere je.” Bibeli kun fun ikilo nipa “buburu” lori awon eniyan. Ka ma baa won enia elese lopo nitoripe yio jasi didanwo ohun tan se. Iwa awon to wa pelu wa yio yo si wa lara. Nitori naa ni o ti dara lati fi gbogbo aye wa ati ti awon to feran Oluwa ti o si aye won le lowo.

Wa ore kan tabi meji, boya ni ile ijosin re, ti o le ran e lowo tabi ba o soro (Heberu 3:13; 10:24). Ba ore re soro wipe ki o ma to e sona lati ma bere nipa idake roro re, ohun ti on se, ati igbese re pelu oluwa. Bere boya o le se be naa fun ohun naa. Eyi ko gbodo je wipe ki o fi awon ore re sile ti won mon Oluwa Olorun Olugbala. Gege bi ore won ko si ni ife won. Je kan mon wipe Oluwa ti so e di atunbi, o si le ma se ohun ti on ba won se tele. Bere lowo Oluwa ki o fun o e ni aye lati baa won ore re soro nipa Jesu.

5. Gba iribomi

Opolopo eniyan ni ohun ti an pe ni iribomi ko ye. Gbolohun ‘iribomi’ fi han wipe ki a ri eniyan sinu omi. Iribomi je ona Bibeli nipa jije ki awon enia mon nipa igbal re ninu Kristi ati itona si re lati tele. Iribomi sinu omi fihan wipe a ti sin o pelu Kristi. Jijade ninu omi naa fihan wipe Kristi jinde. Iribomi fihan wipe iwo fi ara re han pelu iku Jesu, sisin re, ati ajinde re (Romu 6:3-4).

Iribomi ki se igbala. Iribomi ki se wiwe ese wan u. Iribomi je igbese ona ofin, ki o si fi enu re so pelu igbagbo ninu Kristi fun igbala re. Iribomi se pataki nitoripe ona ofin ni- ki wo fi enu re so ni gbangba nipa igbagbo ninu Kristi ati igbesi aye re si owo re. Ti iwo ba ti se tan lati se iribomi, ba oluso agutan re soro.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Mo sese fi igbagbo mi sinu Jesu ... Leyin naa?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries