settings icon
share icon
Ibeere

Kini kristiani?

Idahun


Iwe awon onitumo ti Webster so nipa kristiani “Enia ti o gbagbo ninu Jesu gege bi Kristi tabi nipa esin kiko Jesu.” Gege bi eyi se je igbese rere lati ni oye nipa kristiani, gege bi awon elomi ran si ti tumo re, o je ge bi ohun ti ko so idi naa dada nipa nipa otito bibeli lati le mo itumo kristiani.

Ona meta ninu iwe majemu titun ni a ti lo gbolohun kristiani (Ise awon Aposteli 11; 26: 26; 28: 1 Peteru 4; 16). Awon omo lehin Jesu Kristi ni won koko n pe ni “kristiani” ni Antioku (Ise Awon Aposteli 11; 26) nitori iwa won, ise won ati pe oro won bi Kristi ni. Awon ti o ti ni igbala ni Antioku ni won pe be lati fi won se yeye, won si n pe won ni Kristiani. Itumo eyi ni wipe, “Egbe ara awon Kristi” tabi “omo lehin Kristi”. Eyi si sumo ohun ti itumo iwe Webster pe.

Leyin igba die, gbolohun naa”Kristiani” ko fi le je ikan gidi nitori pe a ma n lo fun elesin tabi eni ti o ni iye nipa nkan biko se atubi ninu Oluwa ati omo leyin Jesu Kristi. Awon eniyan ti ko gbagbo ti ko si ni ireti ninu Jesu ma n pe ra won ni Kristiani nitori pe won ma n lo ile ijosin tabi won gbe inu ilu ti o je Kristiani. Sugbon, ki ama lo si ile ijosin, ki a ma te ri ba fun awon to da ju wa lo, tabi ki a je enia gidi ko ja si wipe kristiani ni wa. Bi oniwasu “li lo ile ijosin o ja si wipe Kristiani ni o, o da bi eni to o lo si ibi ti won ti n tun oko se, iyen o ni wipe o mekaniki ni o. “Bi omo ile ijosin, ki o si ma gbo iwasu dede, ki o si ma se ise ni ile ijosin, ko so e di Kristiani.

Bibeli ko w ape ise rere owo wa ko le je ohun ti ere lowo Olowa. Titu 3;5 wipe, “ki se nipa ise ti awa se ninu ododo sugbon , geg bi anu re li o gba wa la, nipa iwenu atunbi ati isodi titun Emi Mimo. Nitori naa, kristiani je enia to o je atubi ninu Oluwa (Johannu 3:3; Johannu 3;7, 1 Peteru 1; 23) ti won si fi igbagbo ati ireti won si inu Jesu Kristi. Efesu 2;8 so wipe, “ Nitori ore-ofe li a ti fi gba nyin la nipa igbagbo; ati eyini ki ise ti enyin tikaranyin; ebun Olorun ni.” Eni to je kristiani gidi ni enia ti o ti toro idariji ese ti o si fi igbagbo ati ireti re sinu Jesu Kristi nikan. Ireti won ko si ninu esin, ohun igbagbo omo enia tabi ohun to ye ka se, ti ko ye ki a se.

Kristiani gidi je enia ti o fi igbagbo ati ireti re si inu Jesu Kristi ti o si mo n wipe o ku lori igi agbelebu lati rawapada lowo ese, ti o si jinde ni ojo keta lati gbako so lori iku, ki o si fun wa ni iye ainipekun ni fun awon ti o ni igbagbo ninu re. Johannu 1; 12 wipe, “sugbon iye awon ti o gba a awon li o fi agbara fun lati di omo Olorun ani awon na ti o gba oruko re gbo.”

Kristiani gidi je omo Olorun ni toto, ebi omo Olorun, eni ti si fun ni igbesi aye titun ninu Kristi. Ohun ti a fi le da kristiani gidi mo n ni ife ti a ni si ara wa, omo leyin keji wa ati ofin Oluwa ti a pa mo n ninu oro re. (1 Johannu 2;4, 1 Johannu 2;10).

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini kristiani?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries