settings icon
share icon
Ibeere

Ba wo ni mo sele je olododo ninu Oluwa?

Idahun


Ki a le je “olododo” pelu Oluwa, a ni lati mo pe idahun naa ni ese. “Gbogbo won li o si jumo ya si apakan, nwon si di eleri patapata; ko si eniti n se rere, ko si enikeni” (Orin Dafidi 14;3), “Gbogbo wa ti sina kirikiri bi agutan” (Isaiah 53;6).

Iroyin ibanuje ere ese re si ni iku. “emi ti o ba se, iku ni ere re” (Esekieli 18;4). Iroyin ayo ni wipe ife Oluwa ti ranwa lowo lati rawa pada. Jesu so wipe idi ti ohun fi wa ni wipe, “Omo enia de lati wa awon ti o nu kiri ati lati gba won la” (Luku 19;10). O si fi idi re mule nigba ti o pari ohun ti Oluwa ran, nigbati o ku lori igi agbelebu pelu oro re, “O pari! (Johannu 19;30).

Nipa jeje olododo pelu Oluwa, a ni lati gba pe elese niwa. “Nigba na ao bere fun idariji ese lowo Oluwa (Isaiah 57;15) ati igbagbo lati gbagbe ese wa.” “Nitori okan li a fi igbagbo si ododo; enu li a si fi ijewo si igbala” (Romu 10;10).

Idariji ese yi ni lati ni igbagbo. Ni mimo, igbagbo Jesu, iku re,ati iyanu ajinde re je ohun ti o le rawapada.“pe, bi iwo ba fi enu re jewo Jesu li Oluwa, ti iwo si gbagbo li okan re pe, Oluwa jinde kuro ninu oku, a ogba o la” ( Romu 10;9). Awon ori iwe miran si soro nipa igbagbo gidi gan, bi Johannu 20;27; Se awon aposteli 16;31, Galatia 2;16,26, ati efesu 2;8.

Jije olododo ninu Oluwa jasi ohun igbese aye re nipa ohun ti Oluwa ti se fun o. o ran olugbala wa, o pese odo agutan lati gbe ere ese wa kuro (Johannu 1;29), o si fihan fun w ape; enikeni ti o b ape oruko oluwa, a o gba a la ( Ise Awon Aposteli 2;21).

Eyi ti o da ra gidi gan lati fi han nipa itoro aforiji ati nipa idariji ese ni owe agbana omo (Luku 15;11-23). Eyi aburo re si ba gbogbo ohun ti baba re fun je tan, ninu itiju ese re (ori 13). Nigbati o si ranti ohun ibanuje ti o se, o si se ipinu lati pada si ile re (ori 18). O ti ro wipe ohun to si eni ti baba re ma gba pada gege bi omo( ori 19). Sugbon ko ri be. Ife ni baba re ni si nigba ti omo re pada (ori 20). O si da ri ji, gbogbo ese re, won si se ariya (ori 24).

Oluwa dara lati pa ileri re mo, ileri ese.“ Oluwa mbe leti odo awon ti ise onirobinje okan, o si gba iru awon ti ise onirora okan la” (Orin Dafidi 34; 18).

Ti iwo ba fe je olododo ninu Jesu Kristi, gba adura soki yi. Ranti, gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re. “Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi.” Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Ba wo ni mo sele je olododo ninu Oluwa?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries