settings icon
share icon
Ibeere

Nje ajinde wa leyin Iku?

Idahun


Nje ajinde wa leyin Iku? Bibeli so fun wa wipe, “enia ti a ba ninu obinrin o lojo die ni, o si kun fun iponju. O jade wa bi itana ewwko, a si ke e lule, o si nfo lo bi ojiji, ko si duro pe…….. . Bi enia ba ku yio ye bi (Jobu 14;2,14).

Gege bi Jobu, gbogbo wa lati bere ibere yi. Ki ni o ma sele si wa ti a ba ku? Se a koni si mo? Se ile aye yi je gege bi ilekun ti a n gba jade ati ti a n gba wole ninu ile aye lati le ni ogo n la? Nje gbogbo enia lo si ibi ka na, tabi a ma lo si ibi otito? Nje paradise tabi orun apadi wa tabi eyi je ohun okan ti a n ro?

Bibeli so fun wa wipe, “ki se ajinde leyin oku nikan sugbon iye ainipekun ninu ogo ti o ju o ti ri, eti ko ti gbo, okan wa ko mo ohun ti Oluwa ti Oluwa ti pese fun awon to ni ife re,” (1 Korinti 2;9). Jesu Kristi, Olorun eleran ara, wa si ile aye lati wa fun wa ni ebun iye ainipekun. “Sugbon a sa li o gbe nitori ire koja wa, a pa li ara nitori aisedede wa; ina alafia wa wa lara re, ati nipa ina re li afi mu lara da” (Isaiah 53;5).

Jesu gba ese iya to to si o fie mi re lele. Leyin ojo meta, o ni igbala lori iku nigba ti o jinde, pelu emi re ati ara. O durosi inu aye fun ogoji ojo. Awon eniyan pupo ni o si ri ki o to lo si orun ni paradise. Romu 4;25 wipe, “eniti a fi tore ese wa, ti a si jinde nitori idalare wa.”

Ajinde Kristi je ohun ti ko sile dada. Aposteli Paulu so fun awon enia ki won bere lowo awon ti o ri fun idani loju, ko si si eni ti o le ba jinyan o o to naa. Ajinde naa je ohun pataki fun igbagbo kristiani; Nitori Kristi jinde lati inu oku, a le ni igbagbo wipe awa naa le jinde.

Paulu jinyan pelu awon Kristiani akoko ti won gbagbo. “Sugbon so fun mi- Nigba ti a ba kede iroyin ayo wipe Kristi jinde, kini o de tie yin fi so wipe ko si ajinde oku? Nitori pe ti ko ba si ajinde oku, nigba naa Kristi o jinde rara (1 Korinti 15; 12-13).

Kristi nikan ni eni akoko alagbara ti o jinde si ile aye. Iku ti wa lati odo enia kan, Adamu ti o si je ara le wa. Sugbon awon ti o ba gba Olorun gege bi ebi re ninu igbagbo Jesu Kristi la o fun ni aye titun. (1 Korinti 15;20-22). Gege bi Oluwa se jinde ara Jesu, be naa ni ara wa yi o jinde si inu Jesu nigba ti o ba pada wa (1Korinti 6;14).

Sugbon a o jinde, ki se gbogbo enia ni yi o si lo si orun papo. A ni lati se imoran ninu ile aye yi nipa ibi ti a ti fe lo ainipekun wa. Bibeli wipe, “Nwon bi a si ti fi lele fun gbogbo enia lati ku lekan soso, sugbon leyin eyi idajo (Heberu 9;22). Awon ti o se buburu yi o ko ja lo sinu ainipekun; sugbon eni oloto si ni iye ainipekun (Matteu 25;46).

Orun apadi bi orun paradise ki se ibi ti o wa nikan, sugbon ibi ti o je ooto. Ibi ti awon alaigbagbo yi o ti ri ibinu Oluwa ti ko ni opin. Won yio si farada ijiya ara token ati itiju.

Orun apadi dabi iwo ti ko lopin (Luku 8; 31, Ifihan 9:1), ati adagun ina ati sulfuro, nibiti a o ti ma da awon to n gbe inu re loro t’o san- to ru lai ati lailai (Ifihan 20;10). Ni orun apadi, ekun ati ipa eyin keke lati fihan wipe ofo ati ibinu wa ni be (Matteu 13;42). Nibiti kokoro won ki i ku (Marku 9:48). Oluwa ko ni idunu si iku enia buburu, sugbon ki enia buburu yi pada kuro ninu ona re ki o si ye (Esekieli 33;11). Sugbon ko ni fi agidi mo wa lati yipada; ti a ba ko sile, yi o si fun wa ni ohun ti a fe, lati gbe igbe aye ti ko ni si nibe.

Igbe aye wa ni orile aye idanwo ni- imu ra sile fun ohun ti o nbo. Fun awon onigbagbo, aye ailopin ni kaka Oluwa ni o je. Bawo ni a se sowa di eni mimo ti a si le gba iye ailopin? Ona kan ni o wa- Nipa igbagbo ati ireti ninu omo Olorun, Jesu Kristi. Jesu wipe, “Emi ni ajinde, ati iye; eniti o ba gba mi gbo, won ki yo segbe” (Johannu 11;25-26).

Ebun ofe ti oye ailopin wa fun gbogbo eniyan, sugbon o gba pe ki a se ara wa, ki a si fi ara wa yi fun oluwa, “eniti o ba gba omo gbo, o ni iye ainipekun; eniti ko ba si gba omo gbo, ki yio ri iye ; sugbon ibinu Olorun mbe lori re (Johannu 3:36). Won ki yio fun ni aye lati yi pada ku ro ninu ese wa leyin igba ti a ba ti ku nitoripe ti a ba ti ri oju Oluwa, awa ko le yan ohun kohun sugbon ki a gbagbo ninu re. o fe ka a wa si odo re pelu igbagbo ati ife ni isisinyi. Ti a ba gba iku Jesu Kristi gege bi irapada kuro ninu ilodi si Oluwa, a wa ki yio gbe igbe aye ti o ni itumo nikan ninu ile aye, sugbon igbe aye ti ko lopin lodo Kristi ni a o si gbe.

Ti o ba fe gba Jesu Kristi gege bi Olugbala, wo adura ranpe yi. Ranti wipe, gbigba adura yi tabi adura mi ran ko le gba o o la. O ni lati ni ireti ninu Jesu Kristi wipe o le dariji ese re ji o. Adura yi je eyi ti o file so fun Oluwa nipa igbagbo re ninu re, ki o si dupe fun idariji re.“Oluwa, mo wipe elese ni mi. mo si mo wipe iya ayeraye to si mi fun ese mi. Sugbon, mo ni ireti ninu Jesu Kristi gege bi olugbala. Mo mo n wipe iku ati ajinde re lo fun mi ni idariji ese. Mo ni ireti ninu Jesu, Jesu ni kan gege bi Olorun ni nikan ati olugbala mi. E se fun ore- ofe ati idariji ese mi- ebun ayeraye! Ami!

Nje o ti se ipinu fun Kristi nitoripe ohun ti o ti ka ninu oju ewe yi. To ba jebe, jowo te “Mo ti gba Kristi ni oni” ni abe.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Nje ajinde wa leyin Iku?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries