settings icon
share icon
Ibeere

Tani Emi Mimo naa?

Idahun


Awon enia ko mo eni ti Emi Mimo je, Elo miran ni wipe Emi mimo je bi agbara kan. Awon elomiran gbagbo wipe Emi mimo je gege bi alagbara kan ti Oluwa fun Jesu Kristi lati tele. Kini Bibeli so nipa eni ti Emi Mimo je? O so wipe- Emi Mimo ni Olorun. Bibeli si so fun wa wipe enia ni Emi Mimo, Emia to ni opolo, okan ati ona re.

Nitoripe Emi Mimo je Olorun, o si fi han ninu Bibeli daradara bi Ise Awon Aposteli 5:3-4. inu ori yi, peteru do ju ko Ananay nipa wipe bawo ni o se ma paru mo Emi Mimo, sugbon o so fun wipe ko paro mo omo enia sugbon Emi Mimo.” Eyi fi ye wa wipe iro pipa si Emi Mimo na si ni si Olorun. A si le mo wipe Emi Mimo si naa ni Olorun nitori pe o ni gbogbo ohun rere Oluwa. Ti a ba wo, nipa wipe Emi Mimo wa ni ibi gbogbo fi han ni Orin Dafidi 139: 7-8 “Nibo ni o gbe lo kuro lowo emi re? Tabi nibo li emi o sare kuro niwaju re? Bi emi ba gboke lo si orun, iwo wa nibe: bi emi bi emi ba si te eni mi ni ipo oku, kiyesi i, iwo wa nibe.” Leyin naa o ri ninu 1 Korinti 2;10, Emi Mimo ti o le se ohun gbogbo, “Sugbon Olorun ti si won paya fun wa nipa Emi re, nitoripe Emi ni nwadi ohun gbogbo, ani, ohun ijinle ti Olorun.”

A mo wipe Emi Mimo je alaye nitoripe o ni opolo tire, okan re, ati ona re. Emi Mimo ma n ro iro tire, o si mo (1 Korinti 2;10). A le bi Emi Mimo ninu (Efesu 4:30). O si ma ran wa lowo ( Romu 8: 26-27). Emi Mimo je ohun ifihan fun olukaluku enia lati lati fi jere (1 Korinti 12:7-11). Emi Mimo je Olorun, Iketa “Enia” ti okan meta. Bi Olorun, Emi Mimo je olutunnu ati oluko ni ti Jesu wipe ohun yio je (Johannu 14:16, 26;15:26).

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Tani Emi Mimo naa?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries