settings icon
share icon
Ibeere

Kini Oriki Olorun? Nje ba wo ni Olorun se ri?

Idahun


Iroyin ayo ti a ba se fe se dahun naa, orisirisi ni a mo mon nipa Olorun! Awon ti o ba ti gbe igbese lati mon nipa re le ko ko ka; leyin naa won le lo wo ninu iwe mimo lati le ni oye nipa re. Eyi ti iwe mimo so fun wa je pataki, biko se nipa ohun ti Bibeli wi fun wa, awon oro inu re yi o je ironu omo enia ni kan, ti o si je ainiye nipa Olorun (Jobu 42:7). Ki a so wipe o je pataki lati ni oye nipa bi Olorun se je yi o je ohun ti o ye ka so! Ki a ma se mo nipa re ri o si fa wa sehin, tele ohun miran, sin awon Olorun oniro bi es si Olorun ( Eksodu 20;3-5).

Ohun ti Oluwa fun wa lati mo n nikan ni a le mo. Ikan ninu Oriki olorun ni “imole”, e yi wipe o fi ara re han (Isaiah 60:19, Jakobu 1:17). Eyi ti a mo n wipe Oluwa fi oye ara re han ko gbodo je ohun igbagbe, ki enikeni ma se jiyan naa irorun re (Heberu 4:1). Dida, iwe mimo ati oro naa si di ara (Jesu Kristi) yi o si je ki a mo nipa Olorun.

Eje ki a koko mo wipe Olorun ni o da wa ati wipe a si je dida ra re (Genesisi 1:1, Orin Dafidi 24:1). Olorun so wipe a da omo eniyan ni aworan ara re. Omo enia si leke gbogbo ohun miran, ati won si joba lori ohun gbogbo ( Genesisi 1:26-28). Dida ohun gbogbo jasi airekereke ese wa sugbon a ri ise owo re (Genesisi 3: 17-18; Romu 1;19-20). Ki a si ma wo bi dida ise owo re se to bi to, ti o dara, ti a ko mo nipa idi re ati bi o se je lati mo n ise daradara Oluwa.

Nikika die ninu Oruko Olorun yi o ran wa lowo ninu bi oluwa se je. Ohun niyi;
Elohim- alagbara, alatetekose (Genesisi 1;1)
Adonai – Olorun, ifihan ibasepo Olukoni si iranse (Eksodu 4;10,13)
El Elyon – oga ogo, alagbara giga (Genesisi 14;20)
El Roi – Alagbara ti o ri gbogbo aye (Genesisi 16:13)
El Shaddai – Olorun Olodumare (Genesisi 17;1)
El Olam – Eleda gbogbo ipekun aiye (Isaiah 40;28)
Yahweh – Olorun “Emi ni” itumo re wipe Emi ni Olorun ti o wa (Eksodu 3;13,14)

Ki a si wo oriki naa: Olorun ni eni ti o wa, wipe ko ni ibere ati opin re ko si. Olorun ayeraye (Deuteronomi 33;27 ; Orin Dafidi 90:2 ; 1 Timoteu 1:17). Olorun ko yi pada, eyi je wipe ko le yi pada; Eyi je wipe Oluwa ni a le gbekele. Ki a si ni ireti ninu re (Malaki 3;6: Numeri 23;19: Orin Dafidi 102;26,27). A ko le fi Olorun we elomiran, ko si eni bi re ninu ise re; ko si eni bi re ti a le fi we, a ko mon, ibere ko ni opin, a ko le wa, ise ase sehinyin re ni kan ni a le ni oye re (Isaiah 40;28: Orin Dafidi 145; 3 ; Romu 11;33, 34).

Olowa je olododo, ko si ni irele fun omo enia kankan (Deuteronomi 32;4; Orin Dafidi 18;30 ). Olorun le se ohun gbogbo, alagbara ni; o le se gbogbo ohun ti o ba fe, sugbon ise re fihan wipe iwa re ni (ifihan 19;6, Jeremiah 32;17, 27). Oluwa wa ni ibi gbogbo; o wa ni gbogbo aye; eyi ko je wipe Oluwa ni gbogbo nkan (Orin Dafidi 139.7-13; Jeremiah 23; 23). Oluwa je eni ti o mo ohun gbogbo, o mo ti a naa, oni ati ola, pelu ohun ti a n ro nisinsiyi; Nitoripe o mo ohun gbogo, ise olododo re yi o gbe wa duro (Orin Dafidi 139; 1-5: Owe 5;21).

Okan ni Olorun, ko si elo miran, sugbon ohun nikan ni o le se iyanu ohun ti a ba fe, ohun ni kan ni ale gbega, sin ki a si yinlogo (Deuteronomi 6;4). Oluwa je olododo, ko le de elese; nitori pe olododo ni ki ese wa le ni idariji. Jesu ni lati gbe ipa nipa idajo Olorun nigba ti ese wa lori wa (Eksodu 9 ; 22: Matteu 27; 45-46; Romu 3; 21-26).

Oba ni Oluwa, ise owo re atayedaye; gbogbo ise owo re papo, eyi ti a mo n ati eyi ti mo n ko le yi idi ise owo re pada ( Orin Dafidi 93;1, 95;3, Jeremiah 23;20). Emi ni Oluwa, a ko le ri (Johannu 1;18, 4;24). Meta lokan ni Oluwa, iwe mimo wipe okan in Oruko, bi ko se wipe o to si enia meta- “Baba, Omo, Emi Mimo” (Matteu 28; 19, Mark 1; 9-11), oloto ni Olorun, gbogbo ohun ti o so ni o je, ko le pare be ni ko si yi pada (Orin Dafidi 117;2, I Samueli 15;29).

Mimo ni Oluwa, ko si ni ibasepo pelu ohun ese, ko si feran re. Olorun ri gbogbo ohun esu o si binu si; a si ma n soro nipa ina pelu emi mimo re ninu iwe Bibeli. Olorun ni ina naa (Isaiah 6;3, Habakkuku 1;13, Eksodu 3;2,45, Heberu 12;29). Oluwa dara- didara re, aun re, ibunkun re ati ife re – eyi ni awon oro ti a le so ti o je ki Oluwa dara. Bi ko se nipa ti anu Oluwa awon Oriki re ki yi o fi wa han pelu re. A dupe pe eyi ko je be, o fe mo wa daradara (Eksodu 34;6, Orin Dafidi 31;19, 1 Peteru 1;3, Johannu 3;16,17,3).

“Eyi je ona ti a fe le dahun awon ibere naa nipa bi Olorun se je. E jo wo ki e si ma tele Oluwa wa (Jeremiah 29;13).”

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Kini Oriki Olorun? Nje ba wo ni Olorun se ri?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries