settings icon
share icon
Ibeere

Nje awon Kristiani lati tele ofin Majemu?

Idahun


A ni lati mo wipe ofin ti majemu je titi awon omo israelí, lai je ti Kristiani, awon ofin naa wa fun won lati le gbo oro si Oluwa ki won si tele ( Majemu), awon die wa ninu re lati sin Olorun ( lati sin), awon die wa ninu re lati je ki awon omo israelí yato si ilu miran (ofin onje ati aso won). Sugbon ko si majemu kankan ti an tele loni. Nigbati Jesu ku lori igi agbelebu, o si fi opin si iwe majemu lailai (Romu 10:4; Galatia 3:23-25; Efesu 2:15).

Majemu lailai o to si w amo bikose nipa Majemu titnu ti Kristi (Galatia 6:2 ) to wipe, “ Feran Oluwa, Olorun re pelu aiya re, okan re ati gbogbo inu re. Eyi ni ofin akoko ati eyi ti oju ofin ofin lo. Ekeji ni wipe, feran omo ni keji re ti o ti feran ara re. Gbogbo ofin ati oluso apuntan ni o ni ireti ninu ofin yi” (Matteu 22:37-40). Ti a ba se eyi, a si yori ninu gbogbo ti Kristi fe ki ase, “Nitori eyi ni ife Olorun, pe ki awa ki o pa ofin re mo: ofin re ko si nira” ( 1 Johannu 5:3). Kristiani ko ni lati tele ofin majemu lailai mo. Gege be naa, mesan ninu ofin majemu lailai wa ni iwe majemu titnu ( gbogbo re yato si ofin ojo isinmi). Ni toto, ti a ba feran Oluwa, a ko ni sin awon miran tabi sin ohun miran. Ti a ba feran omo ni keji wa, a ko ni pa won, paro fun won, se iseku se pelu won, tabi ki a mu tabi ki a lo ohun ti ko je tiwa. Ki a fi ye wa wipe a ko tele ofin majemu lailai. A ni lati ni ife si Oluwa ati si omo keji wa. Ti a ba se eyi pelu ireti, Oluwa yio bukun wa.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Nje awon Kristiani lati tele ofin Majemu?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries