settings icon
share icon
Ibeere

Nje Oluwa wa laye? Nje oohun kan wa lati mo wipe Oluwa wa?

Idahun


Nje Oluwa wa laye? O dara wipe orisirisi oro lati bere lori re. Ti a ba wo, opolopo awon enia ni o gbagbo wipe Olorun wa tabi agbara kan wa. Eyi si je ohun igbagbo fun awon ti o mo wipe Oluwa mbe. Fun emi, o ye ki o je ibere awon ti ko gbagbo.

Nitori naa a ko le so wipe ko si Oluwa. Bibeli so fun wa wipe ki a ni igbagbo wipe Oluwa wa, “Sugbon li aisi igbagbo ko se ise lati wu u; nitori eniti o ban nto Olorun wa ko le sai gbagbo pe o mbe, ati pe on ni olusesan fun awon ti o fi ara bale wa a, (Heberu 11; 6). Ti Oluwa ba fe;, o le wa ki o si fi ara re han fun gbogbo agbaye wipe ohun n be. Sugbon ti o ba se be, a ko ni ni igbagbo mo. Sugbon Jesu so fun, “Nitoripe iwo ti ri mi, iwo gbagbo, ibukun ni fun awon ti ko ri mi ti won si gbagbo”(Johannu 20;29).

Eyi ko so fun wa wipe ko si Olorun. Bibeli wipe, “Awon orun n soro ogo Olorun; ati ofurufu nfi ise owo re han. Ojo de ojo nfohun, ati oru de oru nfi imo han. Ko si ohun kan tabi ede kan, nibiti a ko gbo iro won. Iro won la gbogbo aiye ja, ati oro won de opin aiye, ninu won li o gbe pago fun orun”(Orin Dafidi 19;1-4). Ti a ba wo gbogbo ohun ti o da, irawo,orun, gbogbo ise owo re, a mo wipe Oluwa mbe. Ti eyi ko ba to, a o mo wipe Oluwa wa ninu okan wa. Oniwasu 3;11 wipe, “……..pelu o fi aiyeraye si won li aiya, beli enikan ko le ridi ise na ti Olorun nse lati ipilese titi de opin……..”ohun kan wa ninu okan wa ti o je ki a mo wipe Oluwa mbe. Awa le paro re, sugbon Oluwa wa ninu aye wa. Nipa eyi Bibeli so fun wa awon elomiran a nip e ko si Olorun. “Asiwere so ninu okan re wipe ko si Olorun (Orin Dafidi 14;1). Ni gbogbo agbaye, opolopo eniyan, esin, orile ede, iwa ni a mo wipe Oluwa mbe, Ohun kan wa ti a gbagbo nipa re.

Bi Bibeli ti so nipa Oluwa, awon ohun kan wa ti a le jiyan re. ikini, ni wipe a le fi han wipe ohun ti Oluwa so le je ki a mo wipe o n mbe. A o koko mo itumo Oluwa,”Ti elomiran ko le ni itumo re.”

Eyi fi ye wa wipe ti o ba wa, o ga ju wipe ti ko ba wa. O si fi han wipe Oluwa mbe. Ti ko ba si Oluwa, nitori naa, eyi ti ye wa pe a ko le ni Olorun- sugbon eyi ko ni je ka ni itumo Olorun. Ekeji ni wipe, nigbati ile aye ni orisirisi ohun didara a ni lati mo wipe enikeni loda. Ti a ba wo, ti ile aye yi ba sun mo orun tabi ti o ba jina si o le ran wa lowo tabi ki o pawa run. Eyi je ohun iyalenu bi gbogbo ohun ti o da se n se ise re lai je ohun idena si omo eniyan.

Iketa ni wipe, gbogbo ohun ti o ba sele ma n ni ibere. Ohun kan ni o bere ile aye yi, ti gbogbo ohun ti o ri yi fi bere lati odo Olorun. Won ko bere fun rara won. Oluwa ni o da ohun gbogbo. Ikerin naa ni wipe gbogbo ohun ni o ni ofin ti re lati le mo ohun ti o dara ati eyi ti ko dara. Apaniyan, iro pipa, ole jija, ati buburu miran ti ko dara. Ibo ni emi yi ti wa, lati odo Olorun ti o je ka mo wipe awon eyi je ohun ti ko da.

Nipa eyi, Bibeli so fun gbogbo enia won ko ni gbagbo nipa oye Oluwa, sugbon won yio gba iro gbo. Romu 1;25 wipe, “Awon eniti o yi otito Olorun pada si eke, nwon si bon won si sin eda ju Eleda lo, eniti ise olubukun tit lai. Amin. Bibeli wipe ko si ijiyan nipa wipe Oluwa mbe, “Nitori ohun re ti a farasin lati igba dida aiye a ri won gbangba, a nfi oye ohun ti a da mo o, ani agbara ati iwa-Olorun re aiyeraye, ki nwon ki o le wa li airiwe; (Romu 1;20).

Awon eniyan so wipe won ko gbagbo ninu Oluwa nitoripe, “ko je ohun imule”tabi “ko si idi re.”Eyi fi han wipe Oluwa wa, won ni lati tele, lati bere fun idariji ese (Romu 3;23, 6;23). Ti Oluwa ba wa, gbogbo ohun ti a ba se, a ni lati tele. Ti ko ba si Olorun, a le se ohun ti a ba fe. Ona ti awon eniyan mo na niyi wipe oluwa nikan ni o da wa. Oluwa n mbe, awon eniyan si mo wipe o n mbe. Nitoripe awon ko so wipe ko wa laiye je ki a mo wipe oluwa mbe.

Fun mi ni aye lati wipe, Ba wo ni mo se mo wipe Oluwa wa laye? Mo mo wipe Oluwa mbe nitoripe mo ma n ba soro lojojumo. Emi le ma gbo lati odo re bi eni ti o n soro, sugbon mo mo wipe o wa pelu mi, o n to mi sona, ife re wa pelu mi, mo si ni ire re. orisirisi ni o ti sele ni ile aye mi ti ko ni bi mo se so bikose nipa Oluwa. Oluwa ra mi pada, o so mi dotun bikose ki n so nipa re ki n de gbe ga. Eyi le ma ye awon ti ko gbagbo ninu re tabi lati fihan nipa ohun ti o se. Leyin naa, a ni lati mo wipe Oluwa mbe a si ni lati gbagbo (Heberu 11;6). Igbagbo ninu Oluwa, ki se igbese afoju ninu okunkun, sugbon ona imole ninu igbesi aye re ti opolopo enia ti wa.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Nje Oluwa wa laye? Nje oohun kan wa lati mo wipe Oluwa wa?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries