settings icon
share icon
Ibeere

Nje Oluwa mbe? Ba wo ni mo sele mo wipe Oluwa Mbe?

Idahun


A mo wipe Oluwa n be nitori pe o ti fi ara re han si wa ni ona meta: Ni dida aye, ninu oro re, ninu omo re, Jesu Kristi.

Eyi ti a file mo nipa Oluwa n be naa ni ohun ti o da. “Nitori ohun re ti o farasin lati igba dida aiye a ri won gbangba, a nfi oye ohun ti a da mo o, ani agbara ati iwa-Olorun re aiyeraiye, ki nwon ki o le wa li airiwi. (Romu 1;20). Awon orun nsoro ogo Olorun; ati ofurufu nfi ise owo re han (Orin Dafidi 19;1).

Ti n ba ri ago owo he ni arin ogba. Awa o ni so wipe da wa lati ibikibi tabi o ti wa ni be tele. Gege bi awon ti o se ago naa, a so wipe o ni bi a se ti se. Sugbon a o ri ise to dara ati ohun ewa ni igberi ko aye yi. Akoko ago ile aye wa ko je gege bi ago owo sugbon ise owo Oluwa- Bi ile aye se n yi (ati gbogbo ohun ti on yi). Ile aye yi fi ohun ewa re han, eyi ni ofi je wipe awon eniyan jiyan re.

Ti n ba ri oro ti o ru mi ni oju, ma wa eni ti o le ran mi lowo lati so itumo re. Emi a sir o wipe eni ti o fi oro naa ranse ni oye, eni ti o so oro naa. Ba wo ni eje ara wa se ri ? Se eyi ko ru wa loju?

Oluwa o da ile aye yi nikan, sugbon o tun fun wa ni ileri ayeraye si inu okan wa ( Oniwasu 3;11). Omo eniyan mo wipe ile aye yi niriro, wipe ohun kan wa ti o ju ile aye yi lo. Igbesi aye wa fi han ni ese meji- ofin ati gbigbe oluwa ga.

Gbogbo omo eniyan ni o mo nipa ofin ti o ya to si esin si esin. Ni yepere, ohun ife je ti mimo, nitori naa piparo je ohun ti ko dara. Iru eyi- Eyi ti o fe biburu ati didara- Ti o si fi iye naa fun wa.

Nibe naa, gbogbo awon eniyan ni ile aye, tabi gege bi esin, won ni bi won se n juba. Ijuba yato si ara won, eyi ni agbara nla. Ni awo re (Genesisi 1;27)

Oluwa si ti fi ara re han ninu oro re, Bibeli. Lati ori iwe mimo naa, eyi ti o fi ye wipe Oluwa wa (Genesisi 1;1, Eksodu 3;14). Nigbati Benjamini Franklin ko ninu iwe ara re, ko jiyan nipa ara re. Gege be naa, Oluwa o file soro ju lati fi ara re han. Iwe mimo Bibeli ti o tun aye eniyan se, oro gidi re, ati iyanu re ti o fi kiko re han to lati le je ki a mo nipa re.

Ona keta naa ti Oluwa fi ara re han ni omo re, Jesu Kristi (Johannu 14;6-11). Latetekose li oro wa; Olorun si ni oro na, oro naa ni Oluwa……. oro naa si di ara, o si n gbe larin wa (Johannu 1;1,14). Ninu Jesu Kristi ‘Ninu re ni gbogbo ekun iwa-Oluwa ngbe li ara- iyara’(Kolosse 2;9).

Ninu igbesi aye Jesu, ko jiyan iwe ti majemu lailai ati ofin re, o si je ki ohun ifihan nipa ti Jesu le mule (Matteu 5;17). O si se ohun iyanu to po ni oju awon eniyan lati fi han wipe ohun ni (Johannu 21;24-25) ojo meta lehin igba ti a kan mo agbelebu, o si jinde, ti awon eniyan pupo si ri (1 Korinti 15:6). Eyi ti je ki a mo eni ti Jesu je. Bi aposteli Paulu se so, ‘A ko se eyi ni ikoko’ (ise Awon Aposteli 26;26).

A mo wipe awon eniyan ma wa ti won ko gbagbo ninu Oluwa ati oro re. Awon kan si wa wipe ko si bi a sele fi han fun won, won ko ni gbagbo (Orin Dafidi 14;1). Igbagbo ni gbogbo eyi (Heberu 11; 6).

English



Pada si oju ewe Yorùbá

Nje Oluwa mbe? Ba wo ni mo sele mo wipe Oluwa Mbe?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries