settings icon
share icon
Ibeere

Nje igbala nipa igbagbo, tabi igbagbo pelu ise?

Idahun


Eyi je ibere pataki larin awon omo leyin Kristi. Ibere yi je ohun ti o yi i pada- eyi ti o fi je ki awon ile ijosin pinya larin ara won. Ibere yi je ohun ti o pin omo leyin Kristi ati esin kristianiti miran. Nje igbala nikan pelu igbagbo, tabi igbagbo pelu ise? Nje emi ti ni gbala ti n ba gbagbo ninu Jesu, tabi mo ni lati gbagbo ninu Jesu lati le se ohun kan?

Ibere: nipa igbagbo nikan tabi igbagbo pelu ise je ki o nira fun awon elomiran bi Bibeli se so. Wo iwe Romu 3:28, 5:1 ati Galatia 3:24 pelu Jakobu 2:24. Awon elomiran mo iyato Paulu (Igbala nipa igbagbo nikan) ati Jakobu (Igbala nipa ise ). Gege be naa, Paulu ati Jakobu won ko ohun kan papo. Ohun ti awon enia jinyan naa ni igbagbo pelu ise. `Paulu wipe, nipa ti ore-ofe ni a gba yin la nipa igbagbo (Efesu 2:8-9) Jakobu si wipe ore-ofe nipa ise ni. Eyi je ki awo ohun ti Jakobu n so. Jakobu so wipe a le ni igbagbo, ki as i ma ni iwa rere lowo (Jakobu 2:17-18). Jakobu wipe, igbagbo gidi ninu Oluwa yio fun wa ni igbesi ayer ere ati ise daradara (Jakobu 2:20-26). Jakobu o so wipe ore-ofe nipa igbagbo pelu ise, sugbon eni ti o ba ni ore-ofe, nipa igbagbo ni lati ni ise owo rere. Ti enikeni ba ni wipe omo Olorun ni ohun, sugbon ko ni iwa rere lowo- nitori naa, eni naa ko ni igbagbo ninu Kristi (Jakobu 2:14, 17, 20,26).

Paulu so ohun kan naa ninu iwe re. Eso rere ti omo Olorun le ni ninu aye yi wa ninu Galatia 5:22-23. Nigbati won ba ti so fun wa wipe a ni igbala nipa igbagbo, lai je nipa ise owo (Efesu 2: 8-9), Paulu so fun wa wipe, a da wa lati se ohun rere (Efesu 2:10). Paulu ati Jakobu so ohun kan naa. “ Nitorina, bi enikeni ba wa ninu Kristi, o di eda titán; ohun atijo ti koja lo: kiyesi i, nwon si di titán ( 1 Korinti 5:17)! Jakobu ati Paulu fi ye wa nipa igbala ninu Jesu. Wo ko so ni ona to yato si ara won ni sugbon ohun kan naa. Paulu wipe, ore-ofe nipa igbagbo nikan, Jakobu si wipe igbagbo ninu Kristi nipa ise rere.

EnglishPada si oju ewe Yorùbá

Nje igbala nipa igbagbo, tabi igbagbo pelu ise?
Pin oju-iwe yii: Facebook icon Twitter icon Pinterest icon Email icon
© Copyright Got Questions Ministries